Àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ Methodist, nílùú Igbó Ọrà níbi Àyájọ́ Èdè Abínibí lágbàáyé (21/02/25)
Àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ Methodist Grammar School, nílùú Igbó Ọrà fi ijó ìbílẹ̀ dá wa lára yá níbi Àyájọ́ Èdè Abínibí lágbàáyé (Int'l Mother Language Day ) Èdè abínibí wa kò ní parun 🙏